Ki a mo Olohun lokan se pataki ninu isemi aye omoniyan paapaajulo eniti o ba je musulumi ododo. Awon alufa esin tumo gbolohun Attaoheed gegebi imo inu Alukurani Alaponle si ki a maa se Olohun lokan, Oba Aaso nibi ijosin re, eleyii tumo si wipe a ko gbodo sin ohunkohun ti o yato si, ola ti o po ni o wa fun eniti o ba se eleyii.
Idaa okun ibi po je alaamori kan ti Olohun fi maa ngbooro arisiki, O si tun je okunfa emigigun, Olohun si maa nfi se ibukun dukia eniyan, idaibipo je apere pipee igbagbo ati didaa Islam eniyan, ni ida miran, ijakun ebi je okunfa ibidandan Olohun ati ijiya re, ati egbee ati iya, ti yio maa pa alubarika re, ti yio si maa jogun ota sise ati ikorira eni.
Imo je imole ati onaamo, aimokan si je okunkun ati anu, imo pelu igbagbo je agbega laye ati lorun, lilo imo ni eso re, ohun si ni ipinle imo ati erongba lori re, o je oranyan lori awon akeeko imo ki won maa sise too ohun ti won mo, ti won ba se bee, imo naa yio je abamo ati adanu fun won, onimimo ti kii ba lo imo re da gegebii abela ti o ntan imonle fun awon eniyan ti o si yo ara re.
Aanu je okan ninu awon iroyin Olohun ti ola re ga ti o fi royin ara re, O si fi si okan ojise re, o si se ni aami ti o han ninu ofin re, eniti o ba ronu si awon idajo ofin esin patapata, yio ri aanu ni eleyi ti o nhan pelu gbogbo aworan ati awon itumo re nibe, eniti o baa ronu si isemi anabi Muhammad(Ki ike ati ola Olohun maa baa), yio ri aanu ti o duro borogidi ninu iwa re pelu itumo ti o han julo
Fi email re sowo siwa ki o le ma ri awon akole titun