Eleyii ni abala ti o ngbero ati so igbagbo eru si Oluwa re di eleyii ti o ni agbara lati ara mimo awon oruko Olohun ati awon iroyin re, ati sisi oju awon eda si awon aami Olohun ti o wa ni aye ti o da, eleyii ti yio fa ki okan awon eru sopo mo Oluwa won pelu igbe ara lee ati ipaya idiyaje re ati ise afokante esan re, ti eru yio wa maa semi ifayabale ti o kun keke fun iyonu ati igbagbo.
Ki a mo Olohun lokan se pataki ninu isemi aye omoniyan paapaajulo eniti o ba je musulumi ododo. Awon alufa esin tumo gbolohun Attaoheed gegebi imo inu Alukurani ...
Ise afomo ise (Ikhlaas)je ohun ti a fe ti o ga ti gbigbe jusile re si je ewu nla,Olohun ki yio gba ise ayafi ti o ba je ise daadaa,ti o si je eyi ti a fi wa oj ...
Ini igbagbo si awon oruko Olohun ati awon iroyin re je ipile kan ti o tobi ninu awon ipile esin, O si je okunfa kan ninu awon okunfa iwo alijanna eru, bakanna n ...
Olohun daa ina, O si kilo fun awon eru nipa re ki won le baa beru re, O si daa alijanna, O si se awon eru lojukokoro imaa rankan re, iberu Olohun ti ola re ga j ...
Inife Olohun ati ojise re je oranyan kan ninu awon oranyan igbagbo, omoniyan ki yio di musulumi ti o ni igbagbo ayafi ti o ba gbe ife Olohun ati ojise re siwaj ...
Awon alaimokan maa ndapara wipe leyin iku saare ni, oro yi ko ri be rara bikose wipe ohun ti o nbe leyin efa oju eje lo gegebi owe Yoruba, nibo ni won yio fi ib ...
Dajudaju, imaa se ironu nipa awon aami Olohun ati agbara re ti o wa laye, yio jogun inigbagbo si agbara Olohun ati ije okansoso re fun eru ni aye yii, niti paap ...
Kosi isinmi beeni kosi ifayabale fun eru ayafi ki o ni igbagbo si ebubu Olohun ati kadara re, eleyi ni ki o gbagbo wipe ohun ti Olohun ba fe ki o se, ni yio se, ...
Inigbagbo si ojo ikeyin je origun kan ninu awon origun igbagbo, igbagbo omoniyan si ojo ikeyin ko tii pe titi ti yio fi ni igbagbo si awon aamin ojo igbende, el ...
Iberu Olohun ni asoole Olohun fun awon eni isaaju ati eni igbeyin, o si je ipepe awon anabi, ati idanimo awon aayo Olohun, paapaa iberu ni ki eru gbe gagaa di ...
Ninu ohun ti o ye ki musulumi gbe ola fun ni orun ti a mo si Alikiyamo je sugbon opolopo ninu awon omo eda eniyan ni o ko airoju pelu isemi aye nikan eleyii ti ...
Igbarale Olohun Oba ti ola re ga je ohun ti a fe ti o tobi, o si je ase lati odo Olohun ti ola re ga fun awon eru re ti won je onigbagbo olodo, O si pa won lase ...
Melomelo omoniyan ti yio maa se opolopo ijosin fun Olohun sugbon ti o ba de iwaju Olohun, yio ri wipe ofo ni gbogbo ohun ti oun se ni ijosin, ohun ti o fa eleyi ...
Alijanna ogba idera je oja ti o won, eleyi ti o se wipe awon osise nsise nitori re, nibe ni awon oju ti o ntanmole, ti o nrerin ti o ndunnu wa, nibe ni ewa ti o ...
Fi email re sowo siwa ki o le ma ri awon akole titun