Abala ijosin

| 16 Lesson

Irun janmoo je ohun ti laada re po jaburata ju irun ti eniyan ba da ki ninu ile tabi soobu re lo,Anobi ki ike ati ola Olohun maa ba se alaye ije oranyan irun ja ...

Bi o ti je wipe gbogbowa ni a mo wipe ti aso ba doti, o ni bukaata si fifo ki o le ba se anfaani fun eniti o nii, bee naa ni, owo ti Olohun ba bun eda naa ni bu ...

Igba ti o tobi julo ni alubarika ni awon ojo mewa akoko ninu osu dhil-hijjah, nitori wipe o ni ipo ti o ga lodo Olohun oba ti ola re ga, eleyi ti o ntoka si ife ...

Suuru koni wo ohunkohun ayafi ki o ko oso ba nkan naa, beeni, ko ni kuro nibi nkan ayafi ki o ko abuku baa nkan naa.Musulumi gbodo je onisuuru nibi iwuwasi re, ...

Osu Ramadan je osu nla, osu ti awon ilekun alujanna maa ndi sisi sile, ti awon ilekun ina si maa ndi titi pa, dajusaka, Olohun ti sadayanri osu yi pelu alekun a ...

Gbogbo eda ni o ni bukaata si Oluwa won nibi gbigba ohun ti yio se won ni anfaani ati titi ohun ti yio niwon lara danu, lati tun esin ati aye won se, awon eru ...

Dajudaju, Olohun oba alaponle se awon ijosin ti o gbongbon lofin fun wa ni ipari osu Ramadan, eleyiti igbagbo yio maa lekun pelu re, ti yio si maa mu ijosin pee ...

Alukurani je tiira Olohun eleyii ti o sokale lati odo re lati maa je iwe ti yio maa dari gbogbo olugbagbo ododo nibi isemi aye ati esin won, eniti o ba gbe iwe ...

Ipo ti irun wa ni okan muumini je ipo ti o ga, ti yio maa soo ni gbogbo awon asiko re ati ni gbogbo awon isesi re, sugbon, o se se ki awon ohun iseriwa gegebii ...

Osu Ramadan, osu aponle, ni osu yi ni a maa nsi awon ilekun alijanna, a si maa nti awon ilekun ile ina, osu ti Olohun gbola fun lori gbogbo osu ti o ku, Olohun ...

Taani ninu wa ti ko nife ojise Olohun (Ki ike ati ola Olohun maa baa)? Niti amodaju, kosi enikankan ti ko nife re, nje olukuluku wa ni o je olododo nibi apemo ...

Olohun ran anabi Muhammad(Ki ike ati ola Olohun maa baa) ni ise si gbogbo eda patapata, o si muu ise Oluwa re de ogongo, o si pee gbabamifipamo esin, o si fi aw ...

Dajudaju, agboye ijosin ninu esin Islam je agboye alakotan ti o ko gbogbo daadaa ninu alaamori esin ati aye sinu, paapaa ijosin je oruko kan ti o ko gbogbo awon ...

Ojo jimoh je ojo ti o loore julo ninu ojo ti oorun nran nibe, ojo yii ni Olohun daa anabi Adamo, ojo yi si ni asiko igbende yio sele, o je ojo odun fun awon mus ...

Nje enikan ri hajj ati bi o se tobi to, ati igbagbo ti o njo herehere, ati awon ogunlogo awon eniyan bi wonse wa ti won ngbe Olohun ga ti won sii ngbee tobi ti ...

Iranti Olohun(Asikiri) fun okan da gegebi omi fun eja, bawo ni eja se maa semi laisi omi? dajusaka, esin to duro deede ti gbewalongbe wipe ki musulumi maa sopo ...

Fi email re sowo siwa ki o le ma ri awon akole titun

Eya
Ilu
Email